Drops
Droplets
Scripts
Languages
Blog
Kahoot!
Business
Gift Drops
Home
/
Yoruba to American English
/
Àwọn eré-ìdárayá Tó le gan
Words for "Àwọn eré-ìdárayá Tó le gan" in American English
Learn the most common words for "Àwọn eré-ìdárayá Tó le gan" in American English. Click on a word for more information and translations.
Yoruba
American English
fífò sílẹ̀ látinú ọkọ̀-òfurufú pẹ̀lú ohun èlò fìfò
skydiving
fífò sílẹ̀ látòkè gíga pẹ̀lú rọ́bà tí a so mọ́lẹ̀ lẹ́sẹ́ ẹni
bungee jumping
eré ìdárayá eléré-sísá, òkè-gígùn àti fífò-kọjá àwọn ohun ìdènà
parkour
fífi bátà onítáyà púpọ̀ rìn lórí yìnyín
rollerblading
ìdíje fífi alùpùpù sáré lórí pápá
motocross
fífò pẹ̀lú ọkọ̀ òfurufú ayọ́kẹ́lẹ́ ọlọ́wọ́
hang gliding
fífò lát'òkè sílẹ̀ pẹ̀lú ohun agbénifò
base jumping
ìdọ̀bálẹ̀-rìn lórí omi pẹ̀lú pátákó ìléfòó
bodyboarding
ìdúró-rìn lórí omi pẹ̀lú pátákó ìléfòó àsomẹ́sẹ̀
wakeboarding
rírìn tàbí sisáré lórí okùn ti a so mọ́ òpó méjì
slacklining
títi ara ẹni kiri nípa sísomọ́ káìtì tì afẹ́fẹ́ ńgbé kiri
kitesurfing
lílo pátákó àti okùn láti wọ́ tẹ̀lé ọkọ̀ ojú omi
waterskiing
Related topics
Àwọn eré-ìdárayá
Àwọn eré-ìdárayá Omi & Yìnyín
Àwọn eré-ìdárayá Síwájú síi
Gbá Bọ́ọ̀lù!