Drops
Droplets
Scripts
Languages
Blog
Kahoot!
Business
Gift Drops
Home
/
Yoruba to American English
/
Wà ní ìlera!
Words for "Wà ní ìlera!" in American English
Learn the most common words for "Wà ní ìlera!" in American English. Click on a word for more information and translations.
Yoruba
American English
ìbojú-bomú
face mask
àkóràn
infection
ààmì àìsàn
symptom
Agbára ìgbóguntàrùn
immunity
kòkòrò àrùn fáírọọsì
virus
gbé látọwọ́dọ́wọ́
transmission
àìsàn
disease
tó ṣeé kóranni
contagious
àsìkò àárín kíkó àti ìfarahàn àrùn
incubation period
ìtọ́jú
treatment
ìrajà pẹ̀lú ìpáyà
panic buying
ìyanisọ́tọ̀
isolation
fífààyèsílẹ̀ larin ara ẹni
social distancing
ìhámọ́lé láti dènà àtànká àrùn
quarantine
apakòkòrò àrùn lọ́wọ́
hand sanitizer
ìbọ̀wọ́ onírọ́bà
latex gloves
ayọ̀ lódì-lódì
hysteria
àjàkálẹ̀ àrùn káríayé
pandemic
Mo wọn gbígbóná ara mi
I take my temperature.
Mo fàyẹ̀wò ṣàfihàn oríṣi àrùn
I diagnose
Mo fọwọ́ mi
I wash my hands.
Mo lọ sọ́dọ̀ dọ́kítà
I go to the doctor.
Mo lòògùn
I take medicine.
Mo f'òògùn apakòkòrò fọ̀
I clean and disinfect.
Jọ̀wọ́ fọwọ́ bo ẹnu rẹ!
Cover your mouth, please!
Related topics
Ìlera
Ara
Ipò ọkàn
Àwọn ẹ̀yà Ara