Drops
Droplets
Scripts
Languages
Blog
Kahoot!
Business
Gift Drops
Home
/
American English to Yoruba
/
More Challenging Phrases
Words for More Challenging Phrases in Yoruba
Learn the most common words for More Challenging Phrases in Yoruba. Click on a word for more information and translations.
American English
Yoruba
How long to get to the airport?
Ìgbà wo ni a má a dé pápákọ̀-òfurufú?
It takes 3 hours and 55 minutes.
A má a gba wákàtí 3 àti ìṣẹ́jú 55.
Can I pay with credit card?
Ṣe mo lè sanwó pẹ̀lú káàdì owó?
I have been here 5 days.
Mo ti wà níbí fún ọjọ́ 5.
I go running on Mondays.
Mo má a ńlọ sáré lọ́jọọjọ́ Ajé.
I see my parents every month.
Mo má a ńrí àwọn òbí mi lóṣooṣù.
I am going to Italy this year in August.
Mò ńlọ sí Itali lọ́dún yìí lóṣù Kẹjọ.
Cover your mouth, please!
Jọ̀wọ́ fọwọ́ bo ẹnu rẹ!
Related topics
As a human, I...
How I Move
How I Act
What I Do