Drops
Droplets
Scripts
Languages
Blog
Kahoot!
Business
Gift Drops
Home
/
American English to Yoruba
/
Extreme Sports
Words for Extreme Sports in Yoruba
Learn the most common words for Extreme Sports in Yoruba. Click on a word for more information and translations.
American English
Yoruba
climbing
pípọ́nkè
paragliding
eré fífò láti òkè pẹ̀lú páráṣúútì
parachute
agbénifò
glider
ọkọ̀-òfurufú ayọ́kẹ́lẹ́
skydiving
fífò sílẹ̀ látinú ọkọ̀-òfurufú pẹ̀lú ohun èlò fìfò
bungee jumping
fífò sílẹ̀ látòkè gíga pẹ̀lú rọ́bà tí a so mọ́lẹ̀ lẹ́sẹ́ ẹni
parkour
eré ìdárayá eléré-sísá, òkè-gígùn àti fífò-kọjá àwọn ohun ìdènà
motocross
ìdíje fífi alùpùpù sáré lórí pápá
hang gliding
fífò pẹ̀lú ọkọ̀ òfurufú ayọ́kẹ́lẹ́ ọlọ́wọ́
base jumping
fífò lát'òkè sílẹ̀ pẹ̀lú ohun agbénifò
riding bmx
gígun kẹ̀kẹ́ bmx
kitesurfing
títi ara ẹni kiri nípa sísomọ́ káìtì tì afẹ́fẹ́ ńgbé kiri
marathon
ìdíje eré-sísá ọlọ́nàjíjìn
I fall
Mo ṣubú
I damage
Mo bàájẹ́
I take a risk
Mo kojú ewu
Related topics
Song Contest
Friendsgiving
American Football
Baker's Kitchen